Ajá

[1]Ajá
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]| Ajá Domestic dog | |
|---|---|
| Dogs | |
| Ipò ìdasí | |
Ọ̀sìn | |
| Ìṣètò onísáyẹ́nsì | |
| Ìjọba: | |
| Ará: | |
| Ẹgbẹ́: | |
| Ìtò: | |
| Ìdílé: | |
| Ìbátan: | |
| Irú: | |
| Irú-ọmọ: | C. l. familiaris |
| Ìfúnlórúkọ mẹ́ta | |
| Canis lupus familiaris | |
| Synonyms | |
| |

Ajá (Dog) Àjà je ẹranko tí ó ní ẹsẹ̀ mẹ́rin. Wọ́n máa ń sáré kíákíá, wọ́n sì tún máa ń ran awon èniyàn lọ́wọ́,pàápàá jùlọ àwọn èniyàn tí wọn kò lè rí ìran, tí a máa ń pè ní "afọ́jú".
Awon ajá le sáré pèlú iyara ti àádóta kilomita ni wakati ọkan (50km/w). Sugbon o ma yipada fun ajá yato nitori awa ni orisirisi aja.[2]
Awon ajá je dabi kọlọkọlọ, akátá, ati awon ikokò. Awon ajá je lokiki, won ti ran awon ọdẹ lowo lati dẹ àwọn ẹranko.[3]
Kíni Ajá Ilé?
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Nípa Ajá Ilé, n tọ́ka sí ọ̀pọ̀ ọgọ́rùn-ún irú ajá tí a lè rí ní gbogbo àgbáyé lónìí, bí ó ti lẹ jẹ́ pé àwọn ajá yìí yàtọ̀ gedegbe sí ara wọn nípa ìrísí, gbogbo ajá láti orí Chihuahua dé Great Dane, jẹ́ ọmọ irú ẹ̀dá kan náà, tí àn pè ní Canis Familiaris. Èyí ni ó jẹ́ kí wọ́n yàtọ̀ sí ẹranko ajá igbó bíi Coyote, Kọlọkọlọ àti Ìkokò.[https://www.nationalgeographic.com/animals/mammals/facts/domestic-dog 1]
Ọ̀pọ̀ ajá ilé ni àwọn èèyàn n tọ́jú gẹ́gẹ́ bí ohun ìṣeré ṣùgbọ́n ọ̀pọ̀ àwọn ajá yìí ló le máa ṣe ayé fún ra wọn, yálà nínú igbó tàbí láàrin àwọn èèyàn lójú òpópónà, gẹ́gẹ́bí ìwádìí Consumer Insights ṣe fìdí rẹ̀ múlẹ̀ nínú ìwádìí to ṣe lọ́dún 2016 .[4]
Ọ̀kan nínú ìdílé mẹ́ta ní àgbáyé ló ní ajá kan, ti èyí mú kí ajá ilé jẹ́ ohun ọ̀sìn tó gbajúmọ̀ jùlọ lágbayé[5]
Ìpilẹ̀ṣẹ̀ àti Ìdàgbàsókè Ajá
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Gbogbo ajá ló wá láti inú irú ìran ẹranko afara jọ ìkookò, ṣùgbọ́n kìí se Ìkookò grey (Canis Lupus) gẹ́gẹ́ bí ọ̀pọ̀ èèyàn ṣe má n rò. Ní òdodo, ẹ̀rí DNA fi hàn pé ìran ìkookò tí àwọn ajá òde òní wa láti inú ìran náà jẹ́ Eurasia. Bí ó ti wù kí ó rí, àwọn onímọ̀ sayẹnsi sí n ṣe ìwádìí láti mọ̀ dájú irú ẹranko tí ó bí àwọn ajá. [5]
Àkókò tí àwọn ajá ya kúrò lọ́dọ̀ àwọn baba ńlá ìran wọn, tí wọ́n jẹ́ ẹranko igbó náà si jẹ́ ohun ìjìnlẹ̀ ṣùgbọ́n àwọn ìwádìí nípa ẹ̀dá ìran (Genetics) fi hàn pé ó ṣẹlẹ̀ láàrin ọdún 15,000 sí 300,000 sẹ́yìn. [5]
Àwọn nǹkan tó yẹ kó o mọ̀ nípa Ajá
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Yàtọ̀ sí pe Aja n tẹ́lẹ̀ ọmọnìyàn lọ sí ọkọ ọdẹ tàbí dáàbò bo èèyàn, Ajá tún ní àwọn nkan míràn yàtọ̀ ìbáṣepọ̀ tó wà láàrin rẹ̀ àti èèyàn. [6]
• Ajá Má n gbóòórùn ẹni tó ní àìsàn Ìtọ̀ súgà ati àrùn jẹjẹrẹ [7]
• Ajá ní Ìpénpéjú mẹ́ta
• Ajá le gbóòórùn bíi Ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá ju ènìyàn lọ [7]
•Òórùn ìtọ̀ ajá má n jẹ́ kí àwọn ajá míràn mọ irú ajá tó kúrò láàyè yẹn bóyá ọmọ kékeré tàbí àgbà ajá ni, ọkùnrin tàbí obìnrin, ó ṣàìsàn ni, inú rẹ̀ dùn ni tàbí ó ń bínú [7]
Kíni Ìdí tí Ajá fi máa n gbó?
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Gbígbó Ajá jẹ́ ọ̀nà ti Ajá n gbà ba ará wọ́n àti ọmọ ènìyàn sọ̀rọ̀. Gbígbó tàbí kúnkùn Ajá jẹ́ àmì pé ajá míràn ti kọjá àyè rẹ̀ tàbí kí nkankan ti máa dunkókò mọ́ ọ tàbí ó fẹ́ dá wà. Bákannáà, ajá má n gbọ́ nígbà míì tí ìrẹ̀wẹ̀sì bá bá wọn tí wọ́n nílò àkíyèsí ajá míràn tàbí ọmọniyàn .[3]
Ṣíṣe Ìtọ́jú Aja rẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Kí ènìyàn ní ajá jẹ́ ohun ìdùnnú gan-an, ó sì máa ń ní àǹfààní tó pọ̀ fún ẹni tó n sìn wọn. Ṣùgbọ́n níní ajá, wọ́n nílò àwọn nkankan. Ìmọ̀ràn àwọn akọ̀ṣẹ́mọṣẹ wa yóò ràn ọ lọ́wọ́ láti rí i dájú pé ajá rẹ ni Ìlera tó péye àti pé kí inú rẹ̀ dùn. Wo àwọn àpilẹ̀kọ yìí ba se tọ́jú ajá
Ajá ní ẹ̀yà ará tó ń yara ṣiṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ẹ̀yà ara tó yàrá gbóòórùn, lọ́nà jíjìn ju àwa àwa èèyàn lọ. Wọ́n ttun rí nà dáadáa nínú òkùnkùn tàbí mọ́lẹ̀ fẹ́rẹ̀ẹ́, bákannáà Wọ́n gbọ́rọ̀ ní ultrasound àti pé wọ́n tètè má nn dá ariwo mọ̀.
Àwọn Ajá ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọ̀nà láti bá ara wọn sọ̀rọ̀ [8]
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ajá má n lo ọ̀nà nípa oòrùn, àwọn ìró bíi ẹkún,, ìró ìró ìbànújẹ́,,kíkùn, gbígbó ati híhu, wọ́n tún má n lo èdè ara nípa lílo ara wọn, ojú, ìrù, etí àti àwọn ẹsẹ̀ wọn láti fi ohun tí wọ́n fẹ́ sọ hàn.
Orísirísi Ẹ̀yà Ajá
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
▪︎Affenpinscher
▪︎Afghan Hound
▪︎Airidale Terrier
▪︎Akita
▪︎Alaskan Klee Kai
▪︎Alaska Malamute
▪︎American Bulldog
▪︎American English Coonhound
▪︎American Eskimo Dog
▪︎ American Foxhound
▪︎American Hairless Terrier
▪︎American Leopard Hound
▪︎Barbado da Terceira
▪︎Barbet
▪︎Basenji
▪︎Basset Fauvve de Bretagne
▪︎Basset. Hound
▪︎Bavarian Mountain Scent Hound
▪︎Beagle
▪︎Bearded Collie
▪︎Beauceron
▪︎Bedlinton Lackonois
▪︎Belgian Malinois
▪︎Cairn Terrier
▪︎Caluppoh
▪︎Canaan Dog
▪︎Canadian Eskimo Dog
▪︎Cane Corso
▪︎Cardigan Welsh Corgi
▪︎Carolina Dog
▪︎Catahoula Leopard Dog
▪︎Caucasian Shepherd Dog
▪︎Cavalier King Charles Spaniel
▪︎Central Asian Shepherd Dog
▪︎Cesky Terrier
▪︎Dachshund
▪︎Dalmatian
▪︎Dandie Dinmont Terrier
▪︎Danish-Swedish Farmdog
▪︎Deutscher Wachtelhund
▪︎Doberman Pinscher
▪︎Dogo Argentino
▪︎ Dogue de Bordeaux
▪︎Drentsche Patrijshound
▪︎Drever
▪︎Dutch Shepherd
▪︎English Cocker Spaniel
▪︎English Foxhound
▪︎English Setter
▪︎English Springer Spaniel
▪︎English Toy Spaniel
▪︎Entlebucher Mountain Dog
▪︎Estrela Mountain Dog
▪︎Eurasier
▪︎Field Spaniel
▪︎Finish Lapphound
▪︎Finish Spitz
▪︎Flat-Coated Retriever
▪︎French Bulldog
▪︎French Spaniel
▪︎German Longhaired Pointer
▪︎German Pinscher
▪︎German Shepherd Dog
▪︎German Shorthaired Pointer
▪︎German Spitz
▪︎German Wirehaired Pointer
▪︎Giant Schnauzer
▪︎Glem of Imaal Terrier
▪︎Golden Retriever
▪︎Goldon Setter
▪︎Grand Basset Griffon Vendéen
▪︎Great Dane
▪︎Hamiltonstovare
▪︎Hanoverian Scenthound
▪︎Harrier
▪︎Havanese
▪︎Hokkaido
▪︎Hovawart
▪︎Ibizan Hound
▪︎Icelandic Sheepdog
▪︎Irish Red and White Setter
▪︎Irish Water Spaniel
▪︎Irish Wolfhound
▪︎Italian Greyhound
▪︎Jagdterrier
▪︎Japanese Akitainu
▪︎Japanese Chin
▪︎Japanese Spitz
▪︎Japanese Terrier
▪︎Kai Ken
▪︎ KarelianBearDog
▪︎Keeshond
▪︎Kerry Blue Terrier
▪︎Kishu Ken
▪︎Komondor
▪︎Korean Jindo Dog
▪︎Kramfohr Lander Kuvasz
▪︎Labrador Retriever
▪︎Lagotto Ramagnolo
▪︎Lakeland Terrier
▪︎Lancashire Heeler
▪︎Lapponian Herder
▪︎Large Munsterlander
▪︎Leonberger
▪︎Lhasa Apso
▪︎LowChen
▪︎Lucas Terrier
▪︎Maltese
▪︎Manchester Terrier (Standard)
▪︎Manchester Terrier (Toy)
▪︎Mastiff
▪︎Miniasture American Shepherd
▪︎Miniature Schnauzer
▪︎Mountain Cur
▪︎Mudi
▪︎Neapolitan Mastiff
▪︎Nederlandse Kooikerhondje
▪︎Nenets Laika
▪︎Newfound Land
▪︎Norfork Terrier
▪︎Norrbottenspets
▪︎Norwegian Buhund
▪︎Norwegian Elkhound
▪︎Norwegian Lundehund
▪︎Norwish Terrier
▪︎Nova Scotia Duck Tolling Retriever
▪︎Old Danish Pointer
▪︎Old English Sheepdog
▪︎Otterhound
▪︎Papillon
▪︎Person Russell Terrier
▪︎ Pekingese
▪︎Pembroke Welsh Corgi
▪︎Peruvian Inca Orchid
▪︎Petit Basset Griffon Vendéen
▪︎Pharaoh Hound
▪︎Plott Hound
▪︎Pointer
▪︎Polish Lowland Sheepdog
▪︎ Pomeranian
▪︎Poin-Audemer Spaniel
▪︎Rageiro do Alentelo
▪︎Rat Terrier
▪︎Redbone Coonhound
▪︎Rhodesian Csrpathian Shepherd
▪︎Rottweiler
▪︎Russell Terrier
▪︎Russian Toy
▪︎Russian Tsventnaya Bolonka
▪︎Saarloos Wolfhound
▪︎Saint Bernard
▪︎Saluki
▪︎Samoyed
▪︎Schipperke
▪︎Scottish Terrier
▪︎Sealyham Terrier
▪︎Segugio Italiano
▪︎ Shetland Sheepdog
▪︎Shiba Inu
▪︎Taiwan Dog
▪︎Teddy Roosevelt Terrier
▪︎ Thai Bangkaew
▪︎Thai Ridgeback
▪︎Tibetan Mastiff
▪︎Tibetan Spaniel
▪︎Tibetan Terrier
▪︎Transylvanian Hound
▪︎Treeing Tennessee
▪︎Vizsla
▪︎Volpino Italiano
▪︎Weimaraner
▪︎Welsh Springer Spaniel
▪︎Welsh Terrier
▪︎West Highland White Terrier
▪︎Wetterhoun
▪︎Whippet
▪︎Wirehaired Vizsla
▪︎Working Kelpie
▪︎Xoloitzcuintli
▪︎Yakutian Laika
▪︎Yorkshire Terrier

Àwọn miiran ajá ti awa ni je "hounds" tumo si ni èdè Yoruba je "oninunibini" awa n pe won yi nitori pé won n lo àwọn hounds lati se inunibini si àwọn ẹranko miiran dabi ehoro ati agbonrin. [9] Ati won n lo àwọn ajá ibọn lati wa ati mo ipo ti àwọn ẹranko ti o le parada ati pamó ara won dada. Àwọn ajá yii, ajá ibon si wa àwọn eye aparo ati àwọn eranko kékeré.[9]

| Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://www.akc.org/dog-breeds/?letter=C
- ↑ https://www.rover.com/blog/how-fast-can-a-dog-run/
- 1 2 https://www.britannica.com/animal/dog
- ↑ https://www.nationalgeographic.com/animals/mammals/facts/domestic-dog
- 1 2 3 https://www.nationalgeographic.com/animals/mammals/facts/domestic-dog
- ↑ https://www.four-paws.org/campaigns-topics/topics/companion-animals/10-facts-about-dogs
- 1 2 3 https://www.four-paws.org/campaigns-topics/topics/companion-animals/10-facts-about-dogs
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: The opening
<ref>tag is malformed or has a bad name. - 1 2 https://vcacanada.com/know-your-pet/hunting-with-your-dog
<ref> tags exist for a group named "https://www.nationalgeographic.com/animals/mammals/facts/domestic-dog", but no corresponding <references group="https://www.nationalgeographic.com/animals/mammals/facts/domestic-dog"/> tag was found.
- ↑ https://www.akc.org/dog-breeds/canadian-eskimo-dog/